Abstract
Bi eto-oselu awujo tabi orile-ede kan ba fe fese rinle pelu itesiwaju to jiire, o to, o si se pataki ki awon eniyan funra won finu-findo gbiyanju lati fi imo sokan pelu igbora-eni-ye nipa sise atunto lati le ri ojutuu si awon nnkan to baje nitori pe ko si ohun to baje koja atunse.

This work is licensed under a Creative Commons Attribution-NonCommercial 4.0 International License.
Copyright (c) 2021 Ayoola Oladunke Aransi, Hakeem Olawale