Abstract
Adébáyọ, baba mi o! ̀ Ọtọ̀ ̀kùlú, Fálétí ni, ọkùnrin ogun Adébáyọ, baba mi o! ̀ Agùntáṣọọ́lò mi ọkùnrin ogun Adébáyọ, baba mi o! ̀ Bọ́bajíròrò lóde Ọyọ̀ ́ ọkùnrin orin Adébáyọ, baba mi o! ̀ Bọ́bagúnwà lóde Ọyọ̀ ́ ọkùnrin orin Ọtọ̀ ̀kùlú akéwì Ọba Ọyọ̀ ́ Aláàfin Adébáyọ, baba mi o! ̀ Ìmùlẹ̀ Àwíṣẹ Wándé Abímbọ́lá baba awo...
This work is licensed under a Creative Commons Attribution-NonCommercial 4.0 International License.