Adébáyọ̀ Fálétí

Abstract

Adébáyọ̀ baba Adébọ́lá! Baba Ọlámilékan!! Mo ń pè ọ́ lóhùn arò, o ò sì jẹ́ mi mọ.́ Òkú ń yan ọmọ rẹ̀ lódì, atoǹtorí ọmọ ọlọmọ. ́ Ìwọ náà kọ, ikú ló kúkú mẹ ́ ́ja kákò bẹẹ́ . ̀ Níjọ́ iṣu kú, mo dabọ n ò jiyán Níjọ́ àgbàdo kú, mo dabọ n ò jẹ̀kọ Níjọ́ ajá mi kú, mo dabọ n ò jẹran abíríkolo Ẹran abíríkolo, àbẹgbẹ ̀ ́ mọ̀ǹdẹ

https://doi.org/10.32473/ysr.v3i2.130002
PDF
Creative Commons License

This work is licensed under a Creative Commons Attribution-NonCommercial 4.0 International License.